YOR Psalm Kapitola 69

Psalm 69

YOR · Porovnať · Audio

1Gbà mí, Ọlọ́run, 2Mo ń rì nínú irà jíjìn, 3Agara dá mi, mo ń pè fún ìrànlọ́wọ́; 4Àwọn tí ó kórìíra mi láìnídìí 5Ìwọ mọ òmùgọ̀ mi, Ọlọ́run; 6Má ṣe dójútì àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ nítorí mi, Olúwa àwọn ọmọ-ogun; 7Nítorí rẹ ni mo ń ru ẹ̀gàn, 8Mo jẹ́ àjèjì si àwọn arákùnrin mi; 9nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run, 10Nígbà tí mo sọkún 11nígbà tí mo wọ aṣọ àkísà, 12Àwọn tí ó jókòó ní ẹnu ibodè ń bú mi, 13Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi ni Olúwa, 14Gbà mí kúrò nínú ẹrẹ̀, 15Má ṣe jẹ́ kí ìkún omi bò mí mọ́lẹ̀ 16Dá mí lóhùn, Olúwa, nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ; 17Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ fún ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ: 18Súnmọ́ tòsí kí o sì gbà mí là; 19Ìwọ ti mọ ẹ̀gàn mi, ìtìjú mi àti àìlọ́lá; 20Ẹ̀gàn ba ọkàn mi jẹ́, 21Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi, 22Jẹ́ kí tábìlì wọn kí ó di ìkẹ́kùn 23Kí ojú wọn kì í ó ṣókùnkùn, kí wọn má ṣe ríran, 24Tú ìbínú rẹ jáde sí wọn; 25Kí ibùjókòó wọn di ahoro; 26Nítorí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí ẹni tí ìwọ ti lù, 27Fi ẹ̀sùn kún ẹ̀sùn wọn; 28Jẹ́ kí a yọ wọ́n kúrò nínú ìwé ìyè 29Ṣùgbọ́n tálákà àti ẹni-ìkáàánú ni èmí, 30Èmi yóò fi orin gbé orúkọ Ọlọ́run ga 31Eléyìí tẹ́ Olúwa lọ́rùn ju ọ̀dá màlúù lọ 32Àwọn òtòṣì yóò rí, wọn yóò sì yọ̀: 33Olúwa, gbọ́ ti aláìní, 34Kí ọ̀run àti ayé yìn ín, 35nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Sioni là 36àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún rẹ̀,

Dosiahnutý dennýLimit

Upgradujte svoj balík, aby ste pokračovali v používaní funkcií AI s vyššími dennými limitmi.

Porovnať všetky plány →