YOR Притчи Глава 24

Притчи 24

1Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburú 2nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ohun búburú, 3Nípa ọgbọ́n ni ilé di kíkọ́ 4nípa ìmọ̀ ni àwọn yàrá rẹ̀ kún 5Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára púpọ̀, 6Láti jagun, ó nílò ìtọ́sọ́nà: 7Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrè 8Ẹni tí ń pète ibi 9Ète òmùgọ̀ ènìyàn jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, 10Bí ìwọ bá dákú lásìkò ìdààmú 11Gba àwọn tí a ń wọ́ lọ sí ibi ikú là; 12Bí ìwọ bá wí pé, “Ṣùgbọ́n a kò mọ nǹkan kan nípa èyí,” 13Jẹ oyin, ìwọ ọmọ mi, nítorí tí ó dára, 14Mọ̀ pẹ̀lú pé ọgbọ́n pẹ̀lú dùn fún ọkàn rẹ 15Má ṣe ba ní ibùba bí ènìyàn búburú 16nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbà méje, yóò tún padà dìde sá á ni, 17Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú; 18Àìṣe bẹ́ẹ̀ Olúwa yóò rí i yóò sì bínú 19Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibi 20nítorí ẹni ibi kò ní ìrètí ọjọ́ iwájú 21Bẹ̀rù Olúwa àti ọba, ọmọ mi, 22Nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn, 23Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú tún jẹ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n: 24Ẹnikẹ́ni tí ó wí fún ẹlẹ́bi pé, “Ìwọ lo jàre,” 25Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi, 26Ìdáhùn òtítọ́ 27Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ 28Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí, 29Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi; 30Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, 31ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, 32Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi 33oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, 34òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè

Дневной лимит достигнут

Обновите свой тариф, чтобы продолжить использовать функции ИИ с более высокими дневными лимитами.

Сравнить все тарифы →