Притчи 20
1Ẹlẹ́yà ni ọtí wáìnì, aláriwo sì ní ọtí líle; 2Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún; 3Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà, 4Ọ̀lẹ kì í ṣiṣẹ́ oko nígbà tí ó yẹ, 5Ète ọkàn ènìyàn dàbí omi jíjìn; 6Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń sọ pe àwọn ní ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn, 7Olódodo ènìyàn a máa gbé ìgbé ayé àìlábùkù 8Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀ láti ṣe ìdájọ́ 9Ta ni ó le è wí pé, “Mo ti ṣe ọkàn mi ní mímọ́, 10Ìwọ̀n èké àti òsùwọ̀n ìrẹ́jẹ Olúwa kórìíra méjèèjì. 11Kódà a mọ ọmọdé nípa iṣẹ́ rẹ̀ 12Etí tí ó ń gbọ́ àti ojú tí ó ń ríran Olúwa ni ó dá méjèèjì. 13Má ṣe fẹ́ràn oorun, àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò di tálákà. 14“Kò dára, kò dára!” ní ẹni tó ra ọjà máa ń wí; 15Wúrà wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹ, 16Gba abọ́ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àlejò; 17Oúnjẹ tí a fi ọ̀nà èrú rí máa ń dùn lẹ́nu ènìyàn, 18Pa ètè rẹ mọ́ nípa wíwá ìmọ̀ràn 19Olófòófó a máa tú àṣírí 20Bí ènìyàn kan bá ṣépè fún baba tàbí ìyá rẹ̀, 21Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀ 22Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.” Olúwa yóò sì gbà ọ́ là. 23Olúwa kórìíra òdínwọ̀n èké. 24Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn. 25Ìdẹ̀kùn ni fún ènìyàn láti ṣe ìlérí kíákíá 26Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká; 27Àtùpà Olúwa ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn 28Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́, 29Ògo àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ni agbára wọn, 30Ìgbájú ìgbámú àti ìfarapa máa ń mú ibi lọ,