YOR Psalm Capitolul 91

Psalm 91

YOR · Comparați · Audio

1ni tí ó gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ọ̀gá-ògo 2Èmi yóò sọ nípa ti Olúwa pé, 3Nítòótọ́ òun yóò gbà mí nínú 4Òun yóò fi ìyẹ́ rẹ̀ bò mí, 5Ìwọ kì yóò bẹ̀rù nítorí ẹ̀rù òru, 6tàbí fún àjàkálẹ̀-ààrùn tí ń rìn kiri ní òkùnkùn, 7Ẹgbẹ̀rún (1,000) yóò ṣubú ní ẹ̀gbẹ́ rẹ, 8Ìwọ yóò máa wò ó pẹ̀lú ojú rẹ 9Nítorí ìwọ fi Olúwa ṣe ààbò rẹ, 10Búburú kan ki yóò ṣubú lù ọ́, 11Nítorí yóò fi àṣẹ fún àwọn angẹli nípa tìrẹ 12wọn yóò gbé ọ sókè ní ọwọ́ wọn, 13Ìwọ yóò rìn lórí kìnnìún àti paramọ́lẹ̀; 14“Nítorí ti ìfẹ́ rẹ sí mi, èmi yóò gbà ọ́; 15Òun yóò pè mí, èmi yóò sì dá a lóhùn; 16Pẹ̀lú ẹ̀mí gígùn ni èmi yóò fi tẹ́ ẹ lọ́rùn,

Limită Zilnică Atinsă

Upgrade-ază-ți planul pentru a continua să utilizezi funcțiile IA cu limite zilnice mai mari.

Compară toate planurile →