YOR Psalm Capitolul 118

Psalm 118

YOR · Comparați · Audio

1 fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó dára; 2Jẹ́ kí Israẹli wí pé: 3Jẹ́ kí ilé Aaroni wí pé: 4Jẹ́ kí àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa wí pé: 5Nínú ìrora mi, mo sọkún sí Olúwa, 6Olúwa ń bẹ fún èmi; èmi kì yóò bẹ̀rù. 7Olúwa ń bẹ fún mi; òun ni olùrànlọ́wọ́ mi. 8Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé Olúwa 9Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé Olúwa 10Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yí mi káàkiri, Olúwa èmi gé wọn kúrò. 11Wọ́n yí mi káàkiri ní gbogbo ẹ̀gbẹ́, Olúwa èmi gé wọn dànù. 12Wọ́n gbá yìn ìn yí mi ká bí oyin, Olúwa èmi ké wọn dànù. 13Ìwọ tì mí gidigidi kí n lè ṣubú, Olúwa ràn mí lọ́wọ́. 14Olúwa ni agbára àti orin mi; 15Ohùn ayọ̀ àti ìgbàlà ń bẹ nínú àgọ́ àwọn olódodo: Olúwa ń ṣe ohun agbára! 16Ọwọ́ ọ̀tún Olúwa ní a gbéga; Olúwa ń ṣe ohun agbára!” 17Èmi kì yóò kú, ṣùgbọ́n èmi yóò yè, Olúwa ṣe. 18Olúwa bá mi wí gidigidi, 19Ṣí ìlẹ̀kùn ẹnu-ọ̀nà òdodo fún mi: Olúwa. 20Èyí ni ìlẹ̀kùn Olúwa 21Èmi yóò fi ọpẹ́ fún ọ, nítorí ó dá mi lóhùn; 22Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, 23Olúwa ti ṣe èyí, 24Èyí ni ọjọ́ tí Olúwa dá: 25Olúwa, gbà wá; Olúwa, fún wa ní àlàáfíà. 26Ìbùkún ni ẹni tí ń bọ̀ wá ní orúkọ Olúwa. Olúwa wá. 27Olúwa ni Ọlọ́run, 28Ìwọ ni Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ; 29Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó ṣeun;

Limită Zilnică Atinsă

Upgrade-ază-ți planul pentru a continua să utilizezi funcțiile IA cu limite zilnice mai mari.

Compară toate planurile →