Psalmen 116
1Èmi fẹ́ràn Olúwa, nítorí ó gbọ́ ohùn mi; 2Nítorí ó yí etí rẹ̀ padà sí mi, 3Okùn ikú yí mi ká, 4Nígbà náà ni mo ké pe orúkọ Olúwa: Olúwa, èmi bẹ̀ ọ́, gba ọkàn mi!” 5Olúwa ní oore-ọ̀fẹ́, ó sì ní òdodo; 6Olúwa pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́ 7Padà, ìwọ ọkàn mi, sí ibi ìsinmi rẹ, Olúwa ṣe dáradára sí ọ. 8Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mi 9nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwa 10Èmi gbàgbọ́; nítorí náà mo wí pé, 11Àti nínú ìdààmú mi mo wí pé, 12Kí ni èmi yóò san fún Olúwa 13Èmi yóò gbé ago ìgbàlà sókè Olúwa. 14Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwa 15Iyebíye ní ojú Olúwa 16Olúwa, nítòótọ́ ìránṣẹ́ rẹ ni mo jẹ́; 17Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ Olúwa. 18Èmi yóò mú ìlérí mi sẹ sí Olúwa 19nínú àgbàlá ilé Olúwa Olúwa.