욥기 36
1Elihu sì tún sọ̀rọ̀ wí pé, 2“Fún mi láyè díẹ̀ èmi ó sì fihàn ọ́, 3Èmi ó mú ìmọ̀ mi ti ọ̀nà jíjìn wá, 4Rí i dájú pé ọ̀rọ̀ mi kì yóò ṣèké nítòótọ́; 5“Kíyèsi i, Ọlọ́run ni alágbára, òun kò i sì gàn ènìyàn; 6Òun kì í dá ẹ̀mí ènìyàn búburú sí, 7Òun kì í mú ojú rẹ̀ kúrò lára olódodo, 8Bí ó bá sì dè wọ́n nínú àbà, 9nígbà náà ni ó ń sọ àwọn ohun tí wọn ti ṣe fún wọn, 10Ó sí wọn létí pẹ̀lú sí ọ̀nà ẹ̀kọ́, 11Bí wọ́n bá gbàgbọ́ tí wọ́n sì sìn ín, 12Ṣùgbọ́n, bí wọn kò bá gbàgbọ́, 13“Ṣùgbọ́n àwọn àgàbàgebè ní ayé kó ìbínú jọ; 14Nígbà náà ni ọkàn wọn yóò kú ní èwe, 15Òun gba òtòṣì nínú ìpọ́njú wọn, 16“Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lúpẹ̀lú ó fa wọn yọ láti inú ìhágágá sí ibi gbòòrò, 17Ṣùgbọ́n ìwọ kún fún ìdájọ́ àwọn búburú; 18Nítorí ìbínú ń bẹ, ṣọ́ra kí òtítọ́ rẹ máa bá a tàn ọ; 19Ọrọ̀ rẹ pọ̀ tó, tí wàhálà kì yóò fi dé bá ọ bí? 20Má ṣe ìfẹ́ òru, nígbà tí a ń ké 21Máa ṣọ́ra kí ìwọ ki ó má yí ara rẹ̀ padà sí búburú, 22“Kíyèsi i, Ọlọ́run ni gbéga nípa agbára rẹ̀; 23Ta ni ó là ọ̀nà iṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ fún un, 24Rántí kí ìwọ kí ó gbé iṣẹ́ rẹ̀ ga, 25Olúkúlùkù ènìyàn a máa rí i; 26Kíyèsi i, Ọlọ́run tóbi, àwa kò sì mọ̀ bí ó ti ní òye tó, 27“Nítorí pé òun ni ó fa ìkán omi òjò sílẹ̀, 28tí àwọsánmọ̀ ń rọ̀ ìrì rẹ̀ sílẹ̀, 29Pẹ̀lúpẹ̀lú ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni lè ní ìmọ̀ ìtànká àwọsánmọ̀, 30Kíyèsi i, ó tan ìmọ́lẹ̀ yí ara rẹ̀ ká 31Nítorí pé nípa wọn ní ń ṣe dájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè ènìyàn; 32Ó fi ìmọ́lẹ̀ bo ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì 33Ariwo àrá rẹ̀ fi ìjì hàn ní;