욥기 9
1Jobu sì dáhùn ó sì wí pé, 2“Èmi mọ̀ pe bẹ́ẹ̀ ni ní òtítọ́. 3Bí ó bá ṣe pé yóò bá a jà, 4Ọlọ́gbọ́n nínú àwọn alágbára ní ipa ní Òun. 5Ẹni tí ó sí òkè nídìí tí wọn kò sì mọ́: 6Tí ó mi ilẹ̀ ayé tìtì kúrò ní ipò rẹ̀, 7Ó pàṣẹ fún oòrùn kò sì le è ràn, 8Òun nìkan ṣoṣo ni ó ta ojú ọ̀run, 9Ẹni tí ó dá ìràwọ̀ Beari àti Orioni, 10Ẹni tí ń ṣe ohun tí ó tóbi jù àwárí lọ, 11Kíyèsi i, ó ń kọjá lọ ní ẹ̀bá ọ̀dọ̀ mi, èmi kò sì rí i, 12Kíyèsi i, ó já a gbà lọ, ta ni ó lè fà á padà? 13Ọlọ́run kò ní fa ìbínú rẹ̀ sẹ́yìn, 14“Kí ní ṣe tí èmi ti n o fi ba ṣàròyé? 15Bí ó tilẹ̀ ṣe pé mo ṣe aláìlẹ́bi, èmi kò gbọdọ̀ dá a lóhùn; 16Bí èmi bá sì ké pè é, tí Òun sì dá mi lóhùn, 17Nítorí pé òun yóò lọ̀ mí lúúlúú pẹ̀lú ìjì ńlá, 18Òun kì yóò jẹ́ kí èmi kí ó rí ẹ̀mí mi, 19Bí mo bá sọ ti agbára, wò ó! 20Bí mo tilẹ̀ dá ara mi láre, ẹnu ara mi yóò dá mi lẹ́bi; 21“Olóòótọ́ ni mo ṣe, 22Ohùn kan náà ni, nítorí náà ni èmi ṣe sọ: 23Bí ìjàǹbá bá pa ni lójijì, 24Nígbà tí a bá fi ayé lé ọwọ́ ènìyàn búburú; 25“Ǹjẹ́ nísinsin yìí ọjọ́ mi yára ju oníṣẹ́ lọ, 26Wọ́n kọjá lọ bí ọkọ̀ eèsún papirusi tí ń sáré lọ; 27Bí èmi bá wí pé, ‘Èmi ó gbàgbé arò ìbìnújẹ́ mi, 28Ẹ̀rù ìbànújẹ́ mi gbogbo bà mí, 29Bí ó bá ṣe pé ènìyàn búburú ni èmi, 30Bí mo tilẹ̀ fi ọṣẹ dídì wẹ ara mi, 31síbẹ̀ ìwọ ó gbé mi wọ inú ihò 32“Nítorí Òun kì í ṣe ènìyàn bí èmi, 33Bẹ́ẹ̀ ni kò sí alátúnṣe kan ní agbede-méjì wa 34Kí ẹnìkan sá à mú ọ̀pá Ọlọ́run kúrò lára mi, 35Nígbà náà ni èmi ìbá sọ̀rọ̀, èmi kì bá sì bẹ̀rù rẹ̀;