YOR 욥기 장 25

욥기 25

YOR · 비교 · 오디오

1Nígbà náà ní Bilidadi, ará Ṣuhi, dáhùn wí pé, 2“Ìjọba àti ẹ̀rù ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀, 3Àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ ha ní ìyè bí, 4Èéha ti ṣe tí a ó fi dá ènìyàn láre lọ́dọ̀ Ọlọ́run? 5Kíyèsi i, òṣùpá kò sì lè tàn ìmọ́lẹ̀, 6kí a má sọ ènìyàn tí i ṣe ìdin,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →