YOR 욥기 장 23

욥기 23

YOR · 비교 · 오디오

1Ìgbà náà ni Jobu sì dáhùn wí pé, 2“Àní lónìí ni ọ̀ràn mi korò; 3Háà! èmi ìbá mọ ibi tí èmí ìbá wá 4Èmi ìbá sì to ọ̀ràn náà níwájú rẹ̀, 5Èmi ìbá sì mọ ọ̀rọ̀ tí òun ìbá fi dá mi lóhùn; 6Yóò ha fi agbára ńlá bá mi wíjọ́ bí? 7Níbẹ̀ ni olódodo le è bá a wíjọ́, 8“Sì wò ó, bí èmi bá lọ sí iwájú, 9Ni apá òsì bí ó bá ṣiṣẹ́ níbẹ̀, èmi kò rí i, 10Ṣùgbọ́n òun mọ ọ̀nà tí èmi ń tọ̀, 11Ẹsẹ̀ mí ti tẹ̀lé ipasẹ̀ ìrìn rẹ̀; 12Bẹ́ẹ̀ ni èmi kò padà sẹ́yìn kúrò nínú òfin ẹnu rẹ̀, 13“Ṣùgbọ́n onínú kan ni òun, ta ni yóò sì yí i padà? 14Nítòótọ́ ohun tí a ti yàn fún mi ní í ṣe; 15Nítorí náà ni ara kò ṣe rọ̀ mí níwájú rẹ̀; 16Nítorí pé Ọlọ́run ti pá mi ní àyà, 17Nítorí tí a kò tí ì ké mi kúrò níwájú òkùnkùn,

일일 한도 도달

플랜을 업그레이드하여 더 높은 일일 한도로 AI 기능을 계속 사용하세요.

모든 요금제 비교 →