Salmi 135
1Ẹ yin Olúwa. Olúwa; Olúwa. 2Ẹ̀yin tí ń dúró ní ilé Olúwa, 3Ẹ yin Olúwa: nítorí tí Olúwa ṣeun; 4Nítorí tí Olúwa ti yan Jakọbu fún ara rẹ̀; 5Nítorí tí èmi mọ̀ pé Olúwa tóbi, 6Olúwa ṣe ohunkóhun tí ó wù ú, 7Ó mú ìkùùkuu gòkè láti òpin ilẹ̀ wá: 8Ẹni tí ó kọlu àwọn àkọ́bí Ejibiti, 9Ẹni tí ó rán iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu sí àárín rẹ̀, ìwọ Ejibiti, 10Ẹni tí ó kọlu àwọn orílẹ̀-èdè púpọ̀, 11Sihoni, ọba àwọn ará Amori, àti Ogu, 12Ó sì fi ilẹ̀ wọn fún ni ní ìní, 13Olúwa orúkọ rẹ dúró láéláé; Olúwa, láti ìrandíran. 14Nítorí tí Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀, 15Fàdákà òun wúrà ni èrè àwọn aláìkọlà, 16Wọ́n ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọn kò le sọ̀rọ̀; 17Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò fi gbọ́rọ̀; 18Àwọn tí ń ṣe wọ́n dàbí wọn: 19Ẹ̀yin ara ilé Israẹli, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa, Olúwa. 20Ẹ̀yin ará ilé Lefi, fi ìbùkún fún Olúwa; Olúwa, fi ìbùkún fún Olúwa. 21Olùbùkún ni Olúwa, láti Sioni wá, Olúwa.