Salmi 10
1Èéha ti ṣe, Olúwa, tí ìwọ fi dúró ní òkè réré? 2Nínú àrékérekè ni ènìyàn búburú tí mu aláìlera, 3Nítorí ènìyàn búburú ń ṣògo ìfẹ́ inú ọkàn rẹ̀; Olúwa. 4Ènìyàn búburú kò lè rí nínú ìgbéraga rẹ̀; 5Ọ̀nà rẹ̀ ń gún régé nígbà gbogbo; 6O wí fún ara rẹ̀, “Kò sí ohun tí ó lè mì mí. 7Ẹnu rẹ̀ kún fún ègún àti irọ́ àti ìtànjẹ; 8Ó lúgọ ní bùba nítòsí ìletò. 9Ó ba ní ní bùba bí i kìnnìún nínú pàǹtí; 10Ó ba, ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀; 11Ó wí fún ara rẹ̀, “Ọlọ́run ti gbàgbé; 12Dìde, Olúwa! Gbé ọwọ́ rẹ sókè, Ọlọ́run. 13Èéṣe tí ènìyàn búburú ṣe ń kẹ́gàn Ọlọ́run? 14Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni ó rí wàhálà àti ìrora; 15Ṣẹ́ apá àwọn ènìyàn búburú àti ènìyàn ibi; 16Olúwa ń jẹ ọba láé àti láéláé; 17Ìwọ́ gbọ́, Olúwa, ìfẹ́ àwọn tí a ni lára; 18láti ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní baba àti àwọn ti a ni lára,