YOR Giobbe Capitolo 19

Giobbe 19

YOR · Confronta · Audio

1Ìgbà náà ni Jobu dáhùn, ó sì wí pé: 2“Yóò ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin ó fi máa fi ìyà jẹ mí, 3Ìgbà mẹ́wàá ní yin yọ mi lénu ẹ̀yin ti ń gàn mí; 4Kí a sì wí bẹ́ẹ̀ pé, mo ṣìnà nítòótọ́, 5Bí ó tilẹ̀ ṣe pé ẹ̀yin ó ṣògo si mi lórí nítòótọ́, 6kí ẹ mọ̀ nísinsin yìí pé, Ọlọ́run ni ó bì mí ṣubú, 7“Kíyèsi, èmi ń kígbe pe, ‘Ọwọ́ alágbára!’ Ṣùgbọ́n a kò gbọ́ ti èmi; 8Ó ṣọgbà dí ọ̀nà mi tí èmi kò le è kọjá, 9Ó ti bọ́ ògo mi, 10Ó ti bà mí jẹ́ ní ìhà gbogbo, 11Ó sì tiná bọ ìbínú rẹ̀ sí mi, 12Ẹgbẹ́ ogun rẹ̀ sì dàpọ̀ sí mi, 13“Ó mú àwọn arákùnrin mi jìnà sí mi réré, 14Àwọn alájọbí mi fàsẹ́yìn, 15Àwọn ará inú ilé mi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi kà mí sí àjèjì; 16Mo pe ìránṣẹ́ mi, òun kò sì dá mi lóhùn; 17Ẹ̀mí mi ṣú àyà mi, àti òórùn mi 18Àní àwọn ọmọdékùnrin fi mí ṣẹ̀sín, 19Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi kórìíra mi, 20Egungun mi lẹ̀ mọ́ ara mi àti mọ́ ẹran-ara mi, 21“Ẹ ṣàánú fún mi, ẹ ṣàánú fún mi, 22Nítorí kí ni ẹ̀yin ṣe lépa mi bí 23“Háà! Ìbá ṣe pé a le kọ̀wé ọ̀rọ̀ mi nísinsin yìí, 24Kí a fi kálámù irin àti ti òjé kọ 25Nítorí èmi mọ̀ pé olùdáǹdè mi ń bẹ láààyè 26àti lẹ́yìn ìgbà tí a pa àwọ̀ ara mi run, 27ẹni tí èmi ó rí fún ara mi, 28“Bí ẹ̀yin bá wí pé, ‘Àwa ó ti lépa rẹ̀ tó! 29kí ẹ̀yin kí ó bẹ̀rù,

Limite Giornaliero Raggiunto

Aggiorna il tuo piano per continuare a utilizzare le funzioni AI con limiti giornalieri più elevati.

Confronta tutti i piani →