Giobbe 18
1Ìgbà náà ni Bilidadi, ará Ṣuhi, dáhùn, ó sì wí pé, 2“Nígbà wo ni ẹ̀yin yóò tó fi ìdí ọ̀rọ̀ tì; 3Nítorí kí ni a ṣe ń kà wá sí bí ẹranko, 4Ìwọ fa ara rẹ ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nínú ìbínú rẹ̀; 5“Nítòótọ́ ìmọ́lẹ̀ ènìyàn búburú ni a ó pa kúrò, 6Ìmọ́lẹ̀ yóò di òkùnkùn nínú àgọ́ rẹ̀, 7Ìrìn ẹsẹ̀ agbára rẹ̀ yóò di fífọ; 8Nípa ẹ̀ṣẹ̀ òun tìkára rẹ̀ ó ti bọ́ sínú àwọ̀n, 9Tàkúté ni yóò mú un ní gìgísẹ̀, 10A dẹkùn sílẹ̀ fún un lórí ilẹ̀, 11Ẹ̀rù ńlá yóò bà á ní ìhà gbogbo, 12Àìlera rẹ̀ yóò di púpọ̀ fún ebi, 13Yóò jẹ ẹ̀yà ara rẹ̀; 14A ó fà á tu kúrò nínú àgọ́ tí ó gbẹ́kẹ̀lé, 15Yóò sì máa jókòó nínú àgọ́ rẹ̀ èyí tí í ṣe tirẹ̀; 16Gbòǹgbò rẹ̀ yóò gbẹ níṣàlẹ̀, 17Ìrántí rẹ̀ yóò parun kúrò ni ayé, 18A ó sì lé e láti inú ìmọ́lẹ̀ sí inú òkùnkùn, 19Kì yóò ní ọmọ tàbí ọmọ ọmọ nínú àwọn ènìyàn rẹ̀, 20Ẹnu yóò ya àwọn ìran ti ìwọ̀-oòrùn sí ìgbà ọjọ́ rẹ̀, 21Nítòótọ́ irú bẹ́ẹ̀ ni ibùgbé àwọn