Ezechiele 19
1“Kọ orin ọ̀fọ̀ nítorí àwọn ọmọ-aládé Israẹli 2wí pé: 3Ó sì tọ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ dàgbà, ó sì di kìnnìún tó ní agbára, 4Àwọn orílẹ̀-èdè gbọ́ nípa rẹ̀, 5“ ‘Nígbà tí abo kìnnìún yìí rí pé ìrètí rẹ̀ sì jásí asán, 6Ó sì ń rìn káàkiri láàrín àwọn kìnnìún nítorí pé ó ti lágbára, 7Ó sì wó odi wọn palẹ̀ ó sì sọ àwọn ìlú wọn di ahoro. 8Nígbà náà ni àwọn orílẹ̀-èdè dìde sí i, 9Wọn fi ìwọ̀ gbé e sínú àgò, wọn mú un lọ sí ọ̀dọ̀ ọba Babeli, 10“ ‘Ìyá rẹ dàbí àjàrà nínú ọgbà àjàrà rẹ̀; 11Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ lágbára tó láti fi ṣe ọ̀pá àṣẹ ìjòyè, 12Ṣùgbọ́n ó fà á tu ní ìrunú, 13Báyìí, a tún ún gbìn sínú aṣálẹ̀ 14Iná sì jáde láti ọ̀kan lára ẹ̀ka rẹ̀