Mikeás 4
1Ní ọjọ́ ìkẹyìn Olúwa lélẹ̀ lórí àwọn òkè ńlá, 2Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè yóò wá, Olúwa, Olúwa láti Jerusalẹmu. 3Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ láàrín ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, 4Ṣùgbọ́n olúkúlùkù yóò jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti sọ̀rọ̀. 5Gbogbo àwọn ènìyàn ń rìn, Olúwa. Olúwa 6“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí, 7Èmi yóò dá àwọn arọ sí fún èyí tókù, Olúwa yóò sì jẹ ọba lórí wọn ní òkè ńlá Sioni 8Ní ti ìwọ, ilé ìṣọ́ agbo àgùntàn, 9Kí ni ìwọ ha ń kígbe sókè sí nísinsin yìí? 10Máa yí síyìn-ín sọ́hùn-ún nínú ìrora, Olúwa yóò ti rà ọ́ padà kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ. 11Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ọ̀pọ̀lọpọ̀ Orílẹ̀-èdè kó ara wọn jọ sí ọ. 12Ṣùgbọ́n wọn kò mọ Olúwa; 13“Dìde, kí ó sì máa pa ọkà ìwọ ọmọbìnrin Sioni, Olúwa