Mikeás 1
1Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Mika ará Moreṣeti wá ní àkókò ìjọba Jotamu, Ahasi, àti Hesekiah, àwọn ọba Juda nìwọ̀nyí, ìran tí ó rí nípa Samaria àti Jerusalẹmu. 2Ẹ gbọ́, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn, Olúwa Olódùmarè lè ṣe ẹlẹ́rìí sí yín, 3Wò ó! Olúwa ń bọ̀ wá láti ibùgbé rẹ̀; 4Àwọn òkè ńlá yóò sí yọ́ lábẹ́ rẹ̀, 5Nítorí ìré-òfin-kọjá Jakọbu ni gbogbo èyí, 6“Nítorí náà, èmi yóò ṣe Samaria bí òkìtì lórí pápá, 7Gbogbo àwọn ère fínfín rẹ̀ ni a ó fọ́ sí wẹ́wẹ́ 8Nítorí èyí, èmi yóò sì sọkún, 9Nítorí tí ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ aláìlèwòtán; 10Ẹ má ṣe sọ ní Gati 11Ẹ kọjá lọ ni ìhòhò àti ni ìtìjú, 12Nítorí àwọn tí ó ń gbé ni Marati ń retí ìre, Olúwa wá sí ẹnu-bodè Jerusalẹmu. 13Ìwọ olùgbé Lakiṣi, 14Nítorí náà ni ìwọ ó ṣe fi ìwé ìkọ̀sílẹ̀ 15Èmi yóò sì mú àrólé kan wá sórí rẹ ìwọ olùgbé Meraṣa. 16Fá irun orí rẹ nínú ọ̀fọ̀