1. Ljetopisa 1
1Adamu, Seti, Enoṣi, 2Kenani, Mahalaleli, Jaredi, 3Enoku, Metusela, Lameki, 4Àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti. 5Àwọn ọmọ Jafeti ni: 6Àwọn ọmọ Gomeri ni: 7Àwọn ọmọ Jafani ni: 8Àwọn ọmọ Hamu ni: 9Àwọn ọmọ Kuṣi ni: 10Kuṣi sì bí Nimrodu 11Ejibiti sì bí 12Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu. 13Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, 14àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi, 15àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini, 16àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati. 17Àwọn ọmọ Ṣemu ni: 18Arfakṣadi sì bí Ṣela, 19Eberi sì bí ọmọ méjì: 20Joktani sì bí 21Hadoramu, Usali, Dikla, 22Ebali, Abimaeli, Ṣeba. 23Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani. 24Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela, 25Eberi, Pelegi. Reu, 26Serugu, Nahori, Tẹra, 27àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu). 28Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli. 29Èyí ni àwọn ọmọ náà: 30Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema, 31Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema. 32Àwọn ọmọ Ketura, obìnrin Abrahamu: 33Àwọn ọmọ Midiani: 34Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki. 35Àwọn ọmọ Esau: 36Àwọn ọmọ Elifasi: 37Àwọn ọmọ Reueli: 38Àwọn ọmọ Seiri: 39Àwọn ọmọ Lotani: 40Àwọn ọmọ Ṣobali: 41Àwọn ọmọ Ana: 42Àwọn ọmọ Eseri: 43Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Edomu, kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí Israẹli: 44Nígbà tí Bela kú, Jobabu ọmọ Sera ti Bosra sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 45Nígbà tí Jobabu kú, Huṣamu láti ilẹ̀ Temani sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 46Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ Bedadi tí ó kọlu Midiani ní ìgbẹ́ Moabu, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti. 47Nígbà tí Hadadi sì kú, Samla láti Masreka, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 48Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 49Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 50Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu. 51Hadadi sì kú pẹ̀lú. 52baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni. 53Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari, 54Magdieli àti Iramu.