YOR Proverbes Chapitre 25

Proverbes 25

YOR · Comparer · Audio

1Wọ̀nyí ni àwọn òwe mìíràn tí Solomoni pa, tí àwọn ọkùnrin Hesekiah ọba Juda dà kọ. 2Ògo Ọlọ́run ní láti fi ọ̀rọ̀ kan pamọ́; 3Bí ọ̀run ṣe ga tó tí ayé sì jì 4Mú ìdàrọ́ kúrò lára fàdákà 5Mú ènìyàn búburú kúrò níwájú ọba 6Má ṣe gbé ara rẹ ga níwájú ọba, 7ó sàn kí ó wí fún ọ pé, “Gòkè wá síyìn-ín,” 8Ohun tí o ti fi ojú ara rẹ rí 9Bí o bá ń ṣe àwíjàre rẹ níwájú aládùúgbò rẹ, 10àìṣe bẹ́ẹ̀ ẹni tí ó gbọ́ ọ le dójútì ọ́ 11Ọ̀rọ̀ tí a sọ ní àkókò tí ó yẹ 12Bí i yẹtí wúrà tàbí ohun ọ̀ṣọ́ ti wúrà dáradára 13Bí títutù òjò yìnyín ní àsìkò ìkórè 14Bí ojú ṣíṣú àti afẹ́fẹ́ láìsí òjò 15Nípa sùúrù a lè yí ọba lọ́kàn padà 16Bí ìwọ bá rí oyin, jẹ ẹ́ ní ìwọ̀nba 17Má ṣe máa lọ sí ilé aládùúgbò rẹ nígbà gbogbo 18Bí ọ̀pá, idà tàbí ọ̀kọ̀ tí ó mú 19Bí eyín tí ó bàjẹ́ tàbí ẹsẹ̀ tí ó rọ 20Bí ẹni tí ó bọ́ra kalẹ̀ ní ọjọ́ tí òtútù mú, 21Bí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ, fún un ní oúnjẹ jẹ; 22Nípa ṣíṣe báyìí, ìwọ yóò wa ẹ̀yín iná lé e lórí Olúwa yóò sì san ọ ní ẹ̀san rẹ̀ fún ọ. 23Bí afẹ́fẹ́ gúúsù ti í mú òjò wá, 24Ó sàn láti gbé ní ibi igun kan lórí òrùlé 25Bí omi tútù sí ọkàn tí ń ṣe àárẹ̀ 26Bí ìsun tí ó di àbàtà tàbí kànga tí omi rẹ̀ bàjẹ́ 27Kò dára láti jẹ oyin àjẹjù, 28Bí ìlú tí odi rẹ̀ ti wó lulẹ̀

Limite quotidienne atteinte

Mettez à jour votre plan pour continuer à utiliser les fonctionnalités de l'IA avec des limites quotidiennes plus élevées.

Comparer tous les forfaits →