YOR Proverbes Chapitre 1

Proverbes 1

YOR · Comparer · Audio

1Àwọn òwe ti Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli. 2Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́, 3Láti gba ẹ̀kọ́ ọgbọ́n, òdodo, 4láti fi òye fún onírẹ̀lẹ̀, 5Jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n tẹ́tí kí ó sì ní ìmọ̀ kún ìmọ̀, 6Láti mọ ìtumọ̀ òwe àti ìtán-dòwe, 7Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀, 8Tẹ́tí, ìwọ ọmọ mi sí ẹ̀kọ́ baba rẹ, 9Wọn yóò jẹ́ òdòdó ẹ̀yẹ olóòórùn dídùn lórí rẹ 10Ọmọ mi, bí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bá ń tàn ọ́, 11Bí wọn bá wí pé, “Wá pẹ̀lú wa; 12jẹ́ ká gbé wọn mì láààyè, bí ibojì òkú, 13a ó rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan tó níye lórí 14da ìpín rẹ pọ̀ mọ́ àárín wa, 15ọmọ mi, má ṣe bá wọn lọ, 16Nítorí ẹsẹ̀ wọn ń sáré sí ẹ̀ṣẹ̀, 17Wàhálà asán ni kí ènìyàn máa dẹ àwọ̀n sílẹ̀, 18Àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ń lúgọ fún ẹ̀jẹ̀ ara wọn. 19Báyìí ni ìgbẹ̀yìn gbogbo àwọn tí ń wá èrè àìtọ́; 20Ọgbọ́n kígbe sókè ní pópó 21láàrín ọjà ni ó ti kígbe jáde 22“Yóò ha ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin aláìmọ̀kan yóò fi fẹ́ àìmọ̀kan yín tó? 23Bí ẹ bá ti gbọ́ ìbáwí ì mi ni, 24Ṣùgbọ́n níwọ̀n bí ẹ ti kọ ìpè ní ìgbà tí mo pè 25níwọ́n bí ẹ ti kọ gbogbo ìmọ̀ràn mi, 26Èmi pẹ̀lú yóò fi ìdààmú yín rẹ́rìn-ín; 27Nígbà tí ìyọnu bá dé bá a yín bí ìjì líle, 28“Nígbà náà ni wọn yóò ké pè mí ṣùgbọ́n, èmi kò ní dáhùn; 29Níwọ́n bí wọ́n ti kórìíra ìmọ̀ Olúwa. 30Níwọ́n bí wọn kò ti gbà ìmọ̀ràn mi 31wọn yóò jẹ èrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn 32Nítorí ìrìnkurìn àwọn aláìmọ̀kan ni yóò pa wọ́n 33ṣùgbọ́n ẹnìkan tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwu

Limite quotidienne atteinte

Mettez à jour votre plan pour continuer à utiliser les fonctionnalités de l'IA avec des limites quotidiennes plus élevées.

Comparer tous les forfaits →