Proverbs 22
1Yíyan orúkọ rere sàn ju púpọ̀ ọrọ̀ lọ, 2Ọlọ́rọ̀ àti tálákà péjọpọ̀: Olúwa ni ẹlẹ́dàá gbogbo wọn. 3Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ti rí ibi tẹ́lẹ̀, 4Èrè ìrẹ̀lẹ̀ àti ìbẹ̀rù Olúwa ni ọrọ̀ ọlá, àti ìyè. 5Ègún àti ìdẹ̀kùn ń bẹ ní ọ̀nà aláyídáyidà: 6Tọ́ ọmọdé ní ọ̀nà tí yóò tọ̀: 7Ọlọ́rọ̀ ṣe olórí olùpọ́njú, 8Ẹni tí ó bá fúnrúgbìn ẹ̀ṣẹ̀, yóò ká asán: 9Ẹni tí ó ní ojú àánú ni a ó bùkún fún; 10Lé ẹlẹ́gàn sí ìta, ìjà yóò sì jáde; 11Ẹni tí ó fẹ́ ìwà funfun ti àyà, 12Ojú Olúwa pa ìmọ̀ mọ́, 13Ọ̀lẹ wí pé, “Kìnnìún ń bẹ lóde! 14Ẹnu àwọn àjèjì obìnrin, ihò jíjìn ni; Olúwa wá ni yóò ṣubú sínú rẹ̀. 15Àyà ọmọdé ni ìwà wèrè dì sí; 16Ẹni tó ń ni tálákà lára láti ní ọrọ̀, 17Dẹtí rẹ sílẹ̀, 18Nítorí ohun dídùn ni bí ìwọ bá pa wọ́n mọ́ ní inú rẹ; 19Kí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ lè wà ní ti Olúwa, 20Èmi kò ha ti kọ̀wé ohun dáradára 21kí ó lè mú ọ mọ ìdájú ọ̀rọ̀ òtítọ́; 22Má ṣe ja tálákà ní olè, nítorí tí ó jẹ́ tálákà: 23nítorí Olúwa yóò gbèjà wọn, 24Má ṣe bá oníbìínú ènìyàn ṣe ọ̀rẹ́; 25Kí ìwọ má ba à kọ́ ìwà rẹ̀, ìwọ a sì gba ìkẹ́kùn fún ara rẹ. 26Má ṣe wà nínú àwọn tí ń ṣe ìgbọ̀nwọ́, 27Bí ìwọ kò bá ní nǹkan tí ìwọ ó fi san, 28Má ṣe yẹ ààlà ilẹ̀ ìgbàanì, 29Ìwọ ha rí ènìyàn tí ó ń fi àìṣe ìmẹ́lẹ́ ṣe iṣẹ́ rẹ̀?