Proverbs 19
1Ó sàn kí ènìyàn jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ kò lábùkù 2Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀, 3Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run; Olúwa. 4Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀; 5Ajẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà, 6Ọ̀pọ̀ ń wá ojúrere olórí; 7Gbogbo ará ilé e tálákà ni ó pa á tì, 8Ẹni tí ó gba ọgbọ́n fẹ́ràn ọkàn ara rẹ̀; 9Ajẹ́rìí èké kì yóò lọ láìjìyà 10Kò yẹ aláìgbọ́n láti máa gbé nínú ọláńlá, 11Ọgbọ́n ènìyàn a máa fún un ní sùúrù; 12Ìbínú ọba dàbí kíké e kìnnìún, 13Aṣiwèrè ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀, 14A máa ń jogún ilé àti ọrọ̀ lọ́dọ̀ òbí, Olúwa ni. 15Ọ̀lẹ ṣíṣe máa ń fa oorun sísùn fọnfọn, 16Ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́ ẹ̀kọ́ pa ẹnu rẹ̀ mọ́, 17Ẹni tí ó ṣàánú tálákà, Olúwa ní ó yá, 18Bá ọmọ rẹ wí nítorí nínú ìyẹn ni ìrètí wà; 19Ènìyàn onínú-fùfù gbọdọ̀ gba èrè ìwà rẹ̀; 20Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́, 21Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn, Olúwa ní ó máa ń borí. 22Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀; 23Ìbẹ̀rù Olúwa ń mú ìyè wá; 24Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú àwo oúnjẹ; 25Na ẹlẹ́gàn, òpè yóò sì kọ́gbọ́n; 26Ẹni tí ó ṣìkà sí baba rẹ̀, tí ó sì lé ìyá rẹ̀ jáde 27Ọmọ mi, dẹ́kun láti tẹ́tí sí ẹ̀kọ́, 28Ẹlẹ́rìí búburú fi ìdájọ́ ṣẹ̀sín, 29A ti pèsè ìjìyà sílẹ̀ fún ẹlẹ́gàn;