YOR Salmos Capítulo 99

Salmos 99

YOR · Comparar · Audio

1Olúwa jẹ ọba; 2Olúwa tóbi ní Sioni; 3Kí wọ́n sì yin orúkọ rẹ̀ tí ó tóbi 4Ọba náà ní agbára, ó sì fẹ́ òdodo, 5Gbígbéga ni Olúwa Ọlọ́run wa 6Mose àti Aaroni wà nínú àwọn àlùfáà rẹ̀ Olúwa, ó sì dá wọn lóhùn. 7Ó sọ̀rọ̀ sí wọn nínú ọ̀wọ́n àwọsánmọ̀, 8Olúwa Ọlọ́run wa, ó dá wọn lóhùn; 9Gbígbéga ni Olúwa Ọlọ́run wa Olúwa Ọlọ́run wa jẹ́ mímọ́.

Límite diario alcanzado

Actualiza tu plan para continuar usando funciones de IA con límites diarios más altos.

Comparar todos los planes →