YOR Salmos Capítulo 24

Salmos 24

YOR · Comparar · Audio

1Ti Olúwa ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún rẹ̀, 2nítorí ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ lórí òkun 3Ta ni yóò gun orí òkè Olúwa lọ? 4Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun, 5Òun ni yóò rí ìbùkún gbà láti ọ̀dọ̀ Olúwa, 6Èyí ni ìran àwọn tí ń ṣe àfẹ́rí rẹ̀, Sela. 7Ẹ gbé orí yín sókè, háà! Ẹ̀yin ọ̀nà; 8Ta ni ọba ògo náà? Olúwa tí ó lágbára tí ó sì le, Olúwa gan an, tí ó lágbára ní ogun. 9Gbé orí yín sókè, ẹyin ọ̀nà; 10Ta ni Ọba ògo náà? Olúwa àwọn ọmọ-ogun Sela.

Límite diario alcanzado

Actualiza tu plan para continuar usando funciones de IA con límites diarios más altos.

Comparar todos los planes →