YOR Psalm Chapter 95

Psalm 95

YOR · Compare · Audio

1 wá, ẹ jẹ́ kí a kọ orin ayọ̀ sí Olúwa, 2Ẹ jẹ́ kí a wá sí iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́ 3Nítorí Olúwa Ọlọ́run títóbi ni, 4Ní ọwọ́ rẹ̀ ni ọ̀gbun ilẹ̀ wà, 5Tirẹ̀ ni Òkun, nítorí òun ni ó dá a 6Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a foríbalẹ̀ kí a sìn ín, Olúwa ẹni tí ó dá wa, 7nítorí òun ni Ọlọ́run wa, 8“Ẹ má ṣe sé ọkàn yín le gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ṣe ní Meriba, 9nígbà tí àwọn baba yín dán mi wò 10Fún ogójì ọdún ni èmi fi bínú sí ìran náà; 11Nítorí náà ni mo kéde ìbúra nínú ìbínú mi,

Daily Limit Reached

Upgrade your plan to continue using AI features with higher daily limits.

Compare all plans →