YOR Psalm Chapter 149

Psalm 149

YOR · Compare · Audio

1 fi ìyìn fún Olúwa. Olúwa. 2Jẹ́ kí Israẹli kí ó ní inú dídùn sí ẹni tí ó dá a 3Jẹ́ kí wọn kí ó fi ijó yin orúkọ rẹ̀ 4Nítorí Olúwa ní inú dídùn sí àwọn ènìyàn rẹ̀ 5Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mímọ́ kí ó yọ̀ nínú ọlá rẹ̀ 6Kí ìyìn Ọlọ́run kí ó wà ní ẹnu wọn 7Láti gba ẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè, 8láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba wọn 9Láti ṣe ìdájọ́ tí àkọsílẹ̀ rẹ̀ sí wọn Olúwa.

Daily Limit Reached

Upgrade your plan to continue using AI features with higher daily limits.

Compare all plans →