Psalmen 79
1Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti wá ilẹ̀ ìní rẹ; 2Wọn ti fi ara òkú àwọn ìránṣẹ́ rẹ 3Wọ́n tu ẹ̀jẹ̀ jáde gẹ́gẹ́ bí omi 4Àwa di ohun ẹ̀gàn sí àwọn tí ó yí wa ká, 5Nígbà wo, Olúwa? Ní ìwọ ó máa bínú títí láé? 6Tú ìbínú rẹ jáde sí orílẹ̀-èdè 7nítorí wọ́n ti run Jakọbu 8Má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wa sí wa lọ́rùn 9Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, 10Àwọn orílẹ̀-èdè yóò máa wí pé, 11Jẹ́ kí ìmí ẹ̀dùn oǹdè náà wá síwájú rẹ, 12San án padà sí àyà àwọn aládùúgbò wa nígbà méje Olúwa. 13Nígbà náà àwa ènìyàn rẹ,