YOR Psalmen Kapitel 47

Psalmen 47

YOR · Vergleichen · Audio

1 pàtẹ́wọ́, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn 2Báwo ni Olúwa Ọ̀gá-ògo ti ní ẹ̀rù tó 3Ṣe ìkápá àwọn orílẹ̀-èdè lábẹ́ wa 4Ó mú ilẹ̀ ìní wa fún wa, 5Ọlọ́run tó gòkè lọ tí òun tayọ̀, Olúwa ti òun ti ariwo ìpè. 6Ẹ kọrin ìyìn sí Ọlọ́run, ẹ kọrin ìyìn. 7Nítorí Ọlọ́run ni ọba gbogbo ayé, 8Ọlọ́run jẹ ọba lórí gbogbo kèfèrí; 9Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọ

Tägliches Limit erreicht

Aktualisieren Sie Ihren Plan, um KI-Funktionen mit höheren täglichen Limits weiter nutzen zu können.

Alle Tarife vergleichen →