YOR Isaiah Kapitel 57

Isaiah 57

YOR · Sammenlign · Lyd

1Olódodo ṣègbé 2Gbogbo àwọn tí ń rìn déédé 3“Ṣùgbọ́n ẹ súnmọ́ ìhìn-ín, ẹ̀yin ọmọ aláfọ̀ṣẹ, 4Ta ni ó fi ń ṣẹlẹ́yà? 5Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrín igi óákù 6Àwọn ère tí ó wà ní àárín òkúta dídán 7Ìwọ ti ṣe ibùsùn rẹ lórí òkè gíga tí ó rẹwà; 8Lẹ́yìn àwọn ìlẹ̀kùn yín àti òpó ìlẹ̀kùn yín 9Ẹ̀yin lọ sí Moleki pẹ̀lú òróró olifi 10Àwọn ọ̀nà yín gbogbo ti mú àárẹ̀ ba á yín, 11“Ta ni ó ń pá yín láyà tí ń bà yín lẹ́rù 12Èmi yóò ṣí òdodo yín páyà àti iṣẹ́ yín, 13Nígbà tí ẹ bá kígbe fún ìrànlọ́wọ́ 14A ó sì sọ wí pé: 15Nítorí èyí ni ohun tí Ẹni gíga àti ọlọ́lá jùlọ wí 16Èmi kì yóò fẹ̀sùn kan ni títí láé, 17Inú bí mi nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀kánjúwà rẹ̀; 18Èmi ti rí ọ̀nà rẹ̀ gbogbo, ṣùgbọ́n Èmi yóò wò ó sàn; 19ní dídá ìyìn sí ètè àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ ní Israẹli. Olúwa wí, “Àti pé, Èmi yóò wo wọ́n sàn.” 20Ṣùgbọ́n àwọn ìkà dàbí i ríru Òkun 21“Kò sí àlàáfíà fún àwọn ìkà,” ni Ọlọ́run mi wí.

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →