YOR Isaiah Kapitel 16

Isaiah 16

YOR · Sammenlign · Lyd

1Fi ọ̀dọ́-àgùntàn ṣe ẹ̀bùn 2Gẹ́gẹ́ bí alárìnkiri ẹyẹ 3“Fún wa ní ìmọ̀ràn 4Jẹ́ kí àwọn ìsáǹsá Moabu gbé pẹ̀lú rẹ, 5Nínú ìfẹ́ a ó fi ìdí ìjọba kan múlẹ̀, 6Àwa ti gbọ́ nípa ìgbéraga Moabu, 7Nítorí náà ni àwọn ará Moabu hu, 8Gbogbo pápá oko Heṣboni ti gbẹ, 9Nítorí náà mo sọkún, gẹ́gẹ́ bí Jaseri ṣe sọkún, 10Ayọ̀ àti ìdùnnú ni a ti mú kúrò 11Ọkàn mi kérora fún Moabu gẹ́gẹ́ bí i dùùrù, 12Nígbà tí Moabu farahàn ní ibi gíga rẹ̀, 13Èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa Moabu. 14Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí Olúwa wí pé, “Láàrín ọdún mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ìdè ọgbà rẹ̀ ti máa kà á, ògo Moabu àti àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn rẹ̀ ni a ó kẹ́gàn, àwọn tí ó sálà nínú rẹ̀ yóò kéré níye, wọn yóò sì jẹ́ akúrẹtẹ̀.”

Daglig grænse nået

Opgrader din plan for at fortsætte med at bruge AI-funktioner med højere daglige grænser.

Sammenlign alle planer →