YOR Isaiah অধ্যায় 51

Isaiah 51

1Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ó ń lépa òdodo Olúwa. 2ẹ wo Abrahamu baba yín, 3Dájúdájú, Olúwa yóò tu Sioni nínú Olúwa. 4“Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin ènìyàn mi; 5Òdodo mi ń bọ̀ wá kíkankíkan, 6Gbé ojú rẹ sókè sí àwọn ọ̀run, 7“Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin tí ó mọ ohun òtítọ́, 8Nítorí kòkòrò yóò mú wọn lá bí aṣọ, 9Dìde, dìde! Kí o sì wọ ara rẹ ní agbára Olúwa; 10Ìwọ kọ́ ni ó gbẹ omi Òkun bí 11Àwọn ẹni ìràpadà Olúwa yóò padà wá. 12“Èmi, àní Èmi, èmi ni ẹni tí ó tù ọ́ nínú. 13tí ìwọ sì gbàgbé Olúwa ẹlẹ́dàá rẹ, 14Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ń ṣojo la ó dá sílẹ̀ ní àìpẹ́ jọjọ 15Nítorí Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀. 16Mo ti fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ Olúwa 17Jí, jí! Olúwa 18Nínú gbogbo ọmọ tí ó bí 19Àjálù ìlọ́po ìlọ́po yìí ti dé bá ọ— 20Àwọn ọmọkùnrin rẹ ti dákú; Olúwa ti kún inú wọn fọ́fọ́ 21Nítorí náà ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí a ti ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́, 22Ohun tí Olúwa Olódùmarè yín wí nìyìí, 23Èmi yóò fi lé àwọn apọ́nilójú rẹ lọ́wọ́,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →