YOR Isaiah অধ্যায় 12

Isaiah 12

1Ní ọjọ́ náà ni ìwọ ó wí pé, Olúwa. 2Nítòótọ́ Ọlọ́run ni ìgbàlà mi, Olúwa, Olúwa náà ni agbára à mi àti orin ìn mi, 3Pẹ̀lú ayọ̀ ni ìwọ yóò máa pọn omi 4Ní ọjọ́ náà, ìwọ yóò wí pé, Olúwa, ké pe orúkọ rẹ̀, 5Kọ orin sí Olúwa, nítorí ó ti ṣe ohun tí ó lógo, 6Kígbe sókè kí o sì kọrin fún ayọ̀, ẹ̀yin ènìyàn Sioni,

দৈনিক সীমা পূর্ণ হয়েছে

উচ্চতর দৈনিক সীমা সহ AI বৈশিষ্ট্যগুলি ব্যবহার চালিয়ে যেতে আপনার পরিকল্পনা আপগ্রেড করুন।

সব প্ল্যান তুলনা করুন →