YOR 箴言 章 2

箴言 2

YOR · 比较 · Audio

1mọ mi, bí ìwọ bá gba ọ̀rọ̀ mi, 2tí ìwọ dẹtí rẹ sílẹ̀ sí ọgbọ́n 3àní, bí ìwọ bá ké tọ ìmọ̀ lẹ́yìn, 4bí ìwọ bá ṣàfẹ́rí rẹ̀ bí i fàdákà 5Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀rù Olúwa, 6Nítorí Olúwa ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n, 7Ó to ìgbàlà fún àwọn olódodo, 8Ó pa ipa ọ̀nà ìdájọ́ mọ́ 9Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ òdodo àti ìdájọ́, 10Nítorí ọgbọ́n yóò wọ inú ọkàn rẹ 11Ìmòye yóò pa ọ mọ́ 12Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú, 13ẹni tí ó kúrò ní ọ̀nà ìdúró ṣinṣin 14ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú, 15ọ̀nà ẹni tí ó wọ́ 16Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin, 17ẹni tí ó ti kọ ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀ 18Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú 19Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà 20Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere 21Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náà 22Ṣùgbọ́n a ó ké ènìyàn búburú kúrò lórí ilẹ̀ náà

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →