YOR 何西阿书 章 14

何西阿书 14

YOR · 比较 · Audio

1Yípadà ìwọ Israẹli sí Olúwa Ọlọ́run rẹ. 2Ẹ gba ọ̀rọ̀ Olúwa gbọ́, Olúwa. 3Asiria kò le gbà wá là; 4“Èmi wo àgàbàgebè wọn sàn, 5Èmi o dàbí ìrì sí Israẹli, 6Àṣẹ̀ṣẹ̀yọ ẹ̀ka rẹ̀ yóò dàgbà, 7Àwọn ènìyàn yóò tún padà gbé lábẹ́ òjijì rẹ̀. 8Ìwọ Efraimu, kín ló tún kù tí mo ní ṣe pẹ̀lú ère òrìṣà? 9Ta ni ọlọ́gbọ́n? Òun yóò mòye àwọn nǹkan wọ̀nyí. Olúwa

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →