YOR 雅歌 章 2

雅歌 2

YOR · 比较 · Audio

1Èmi ni ìtànná Ṣaroni 2Bí ìtànná lílì ní àárín ẹ̀gún 3Bí igi ápù láàrín àwọn igi inú igbó, 4Ó mú mi lọ sí ibi gbọ̀ngàn àsè, 5Fi agbára adùn àkàrà dá mi dúró. 6Ọwọ́ òsì rẹ ń bẹ lábẹ́ orí mi 7Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerusalẹmu, 8Gbọ́ ohùn olùfẹ́ mi! 9Olùfẹ́ mi dàbí abo egbin tàbí ọmọ àgbọ̀nrín. 10Olùfẹ́ mi fọhùn ó sì sọ fún mi pé, 11Wò ó! Ìgbà òtútù ti kọjá; 12Àwọn òdòdó fi ara hàn lórí ilẹ̀ 13Igi ọ̀pọ̀tọ́ mú èso tuntun jáde, 14Àdàbà mi wà nínú pàlàpálá òkúta, 15Bá wa mú àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, 16Olùfẹ́ mi ni tèmi èmi sì ni tirẹ̀; 17Títí ìgbà ìtura ọjọ́

已达到每日限制

升级您的计划以继续使用 AI 功能和更高的每日限制。

比较所有套餐 →