YOR Jeremiah Chương 8

Jeremiah 8

YOR · So sánh · Âm thanh

1 ‘Ní ìgbà náà ni Olúwa wí pé, wọn yóò mú egungun àwọn ọba Juda àti egungun àwọn ìjòyè, egungun àwọn àlùfáà àti egungun àwọn wòlíì àti egungun àwọn olùgbé Jerusalẹmu kúrò nínú ibojì. 2A ó yọ wọ́n síta fún oòrùn àti òṣùpá àti gbogbo àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run tí wọ́n ti fẹ́ràn tí wọ́n sì ti sìn, àti àwọn tí wọ́n ti tọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n ti wá tí wọ́n sì ti foríbalẹ̀ fún. Kì yóò ṣà wọ́n jọ tàbí sìn wọ́n, wọn yóò dàbí ìdọ̀tí tó wà lórí ilẹ̀. 3Níbikíbi tí mo bá lé wọn lọ, gbogbo àwọn ìyókù wọn yóò fẹ́ ikú ju ìyè lọ ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.’ 4“Wí fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 5Èéṣe nígbà náà àwọn ènìyàn wọ̀nyí fi yà kúrò lọ́nà rẹ̀? 6Mo ti fetísílẹ̀ dáradára, 7Kódà, ẹyẹ àkọ̀ ojú ọ̀run Olúwa wọn fẹ́. 8“ ‘Báwo ni ẹ̀yin ṣe lè wí pé, “Àwa gbọ́n, Olúwa,” 9Ojú yóò ti àwọn ọlọ́gbọ́n, Olúwa, 10Nítorí náà, èmi yóò fi ìyàwó wọn fún àwọn ọkùnrin mìíràn 11Wọ́n tọ́jú ọgbẹ́ àwọn ènìyàn mi 12Ǹjẹ́ wọ́n tijú fún ìṣe ìríra wọn? Olúwa wí. 13“ ‘Èmi yóò mú ìkórè wọn kúrò, Olúwa wí. 14“Èéṣe tí àwa fi jókòó ní ibí yìí? Olúwa Ọlọ́run wa ti pinnu pé a ó ṣègbé. 15Àwa ń retí àlàáfíà 16Ìró ìfọn imú ẹṣin àwọn ọlọ̀tẹ̀ 17“Wò ó, èmi yóò rán àwọn ejò olóró sí àárín yín, Olúwa wí. 18Olùtùnú mi, nígbà tí ìbànújẹ́ ọkàn mi, 19Fetí sí ẹkún àwọn ènìyàn mi Olúwa kò ha sí ní Sioni bí? 20“Ìkórè ti rékọjá, 21Níwọ́n ìgbà tí a pa àwọn ènìyàn mi run, èmi náà run pẹ̀lú, 22Kò ha sí ìkunra ní Gileadi bí?

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →