YOR Jonah Chương 2

Jonah 2

YOR · So sánh · Âm thanh

1Nígbà náà ni Jona gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ láti inú ẹja náà wá, 2Ó sì wí pé: Olúwa, 3Nítorí tí ìwọ ti sọ mí sínú ibú, 4Nígbà náà ni mo wí pé, 5Omi yí mi káàkiri, àní títí dé ọkàn; 6Èmi sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ àwọn òkè ńlá; Olúwa Ọlọ́run mi. 7“Nígbà tí ó rẹ ọkàn mi nínú mi, Olúwa, 8“Àwọn tí ń fàmọ́ òrìṣà èké 9Ṣùgbọ́n èmi yóò fi orin ọpẹ́, rú ẹbọ sí ọ. Olúwa.’ ” 10Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jona sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →