YOR Ezekiel Chương 7

Ezekiel 7

YOR · So sánh · Âm thanh

1̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá: 2“Ọmọ ènìyàn, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí sí ilé Israẹli: 3Òpin tí dé sí ọ báyìí, 4Ojú mi kò ní i dá ọ sì, Olúwa.’ 5“Èyí ni Olúwa Olódùmarè wí: 6Òpin ti dé! 7Ìparun ti dé sórí rẹ, 8Mo ṣetán láti tú ìbínú gbígbóná mi lé ọ lórí 9Ojú mi kò ní i dá ọ sí, Olúwa lo kọlù yín. 10“ ‘Ọjọ́ náà dé! 11Ìwà ipá ti di ọ̀pá ìwà búburú; 12Àkókò náà dé! 13Nítorí pé òǹtajà kì yóò rí gbà padà 14“ ‘Wọ́n ti fọn ìpè ogun, 15Idà wà ní ìta, 16Gbogbo àwọn tí ó bọ́ nínú wọn yóò sálà, 17Gbogbo ọwọ́ yóò rọ, 18Wọn yóò wọ aṣọ ọ̀fọ̀, 19“ ‘Wọn yóò dà fàdákà wọn sí ojú pópó, Olúwa. 20Wọ́n ń ṣe ìgbéraga pẹ̀lú ohun ọ̀ṣọ́ wọn tí ó lẹ́wà, 21Èmi yóò sì fi àwọn nǹkan wọ̀nyí ṣe ìjẹ fún àjèjì 22Èmi yóò gbójú mi kúrò lára wọn, 23“ ‘Rọ ẹ̀wọ̀n irin! 24Èmi yóò mú kí orílẹ̀-èdè ti ó búburú jùlọ 25Nígbà tí ìpayà bá dé, 26Wàhálà lórí wàhálà yóò dé, 27Ọba yóò ṣọ̀fọ̀, Olúwa.’ ”

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →