YOR Amos Chương 3

Amos 3

YOR · So sánh · Âm thanh

1 gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Olúwa ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Ejibiti: 2“Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yàn 3Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀ 4Ǹjẹ́ Kìnnìún yóò ha bú ramúramù nínú igbó, 5Ǹjẹ́ ẹyẹ ṣubú sínú okùn ọdẹ lórí ilẹ̀ 6Nígbà tí ìpè bá dún ní ìlú, Olúwa ni ó fà á? 7Nítòótọ́ Olúwa Olódùmarè kò ṣe ohun kan 8Kìnnìún ti bú ramúramù Olúwa Olódùmarè ti sọ̀rọ̀ 9Ẹ kéde ní ààfin Aṣdodu 10“Wọn kò mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rere,” ni Olúwa wí, 11Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí: 12Èyí ni ohun tí Olúwa wí: 13“Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jakọbu,” ni Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun. 14“Ní ọjọ́ tí mo fìyà jẹ Israẹli lórí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, 15Èmi yóò wó ilé òtútù Olúwa wí.

Đã đạt giới hạn hàng ngày

Nâng cấp gói của bạn để tiếp tục sử dụng các tính năng AI với giới hạn hàng ngày cao hơn.

So sánh tất cả các gói →