Lamentations 4
1Báwo ni wúrà ṣe sọ ògo dídán rẹ̀ nù, 2Báwo ni àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Sioni tí ó ṣe iyebíye, 3Àwọn ajáko pèsè ọmú wọn 4Nítorí òǹgbẹ, ahọ́n àwọn ọmọ ọwọ́ 5Àwọn tí ó ń jẹ ohun dáradára 6Ìjìyà àwọn ènìyàn mi 7Ọmọ ọba ọkùnrin wọn mọ́ ju òjò-dídì, 8Ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n dúdú ju èédú; 9Àwọn tí ó kù nípasẹ̀ idà sàn 10Pẹ̀lú ọwọ́ àwọn obìnrin aláàánú 11Olúwa ti fi ihò kíkún fún ìbínú rẹ̀; 12Àwọn ọba ayé kò gbàgbọ́, 13Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì 14Nísinsin yìí wọ́n ń rìn kiri ní òpópó 15“Lọ kúrò! Ẹ̀yin di aláìmọ́!” ni àwọn ènìyàn ń kígbe sí wọn. 16Olúwa ti tú wọn ká fúnra rẹ̀; 17Síwájú sí i, ojú wa kùnà 18Wọ́n ń ṣọ́ wa kiri, 19Àwọn tí ń lé wa yára 20Ẹni àmì òróró Olúwa, èémí ìyè wa, 21Ẹ yọ̀ kí inú yín sì dùn, ẹ̀yin ọmọbìnrin Edomu, 22Ìwọ ọmọbìnrin Sioni, ìjìyà rẹ yóò dópin;