YOR Job Розділ 30

Job 30

1Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, 2Kí ni ìwúlò agbára ọwọ́ wọn sí mi, 3Wọ́n rù nítorí àìní àti ìyàn 4Àwọn ẹni tí ń já ewé iyọ̀ ní ẹ̀bá igbó; 5A lé wọn kúrò láàrín ènìyàn, 6A mú wọn gbe inú pàlàpálá òkúta àfonífojì, 7Wọ́n ń dún ní àárín igbó 8Àwọn ọmọ ẹni tí òye kò yé, 9“Ǹjẹ́ nísinsin yìí, àwọn ọmọ wọn ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà nínú orin; 10Wọ́n kórìíra mi; wọ́n sá kúrò jìnnà sí mi, 11Nítorí Ọlọ́run ti tú okùn ìyè mi, ó sì pọ́n mi lójú; 12Àwọn ènìyàn lásán dìde ní apá ọ̀tún mi; 13Wọ́n da ipa ọ̀nà mi rú; 14Wọ́n ya sí mi bí i omi tí ó ya gbuuru; 15Ẹ̀rù ńlá bà mí; 16“Àti nísinsin yìí, ayé mi n yòrò lọ díẹ̀díẹ̀; 17Òru gún mi nínú egungun mi, 18Nípa agbára ńlá rẹ̀ Ọlọ́run wà bí aṣọ ìbora fún mi, 19Ọlọ́run ti mú mi lọ sínú ẹrẹ̀, 20“Èmi ké pè ọ́ ìwọ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ìwọ kò dá mi lóhùn; 21Ìwọ padà di ẹni ìkà sí mi; 22Ìwọ gbé mi sókè sí inú ẹ̀fúùfù, ìwọ mú mi fò lọ, 23Èmi sá à mọ̀ pé ìwọ yóò mú mi lọ sínú ikú, 24“Bí ó ti wù kí ó rí, ẹnìkan kí yóò ha nawọ́ rẹ̀ nígbà ìṣubú rẹ̀, 25Èmi kò ha sọkún bí fún ẹni tí ó wà nínú ìṣòro? 26Nígbà tí mo fojú ṣọ́nà fún àlàáfíà, ibi sì dé; 27Ikùn mí n ru kò sì sinmi, 28Èmí ń rìn kiri nínú ọ̀fọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú oòrùn; 29Èmi ti di arákùnrin ìkookò, 30Àwọ̀ mi di dúdú ní ara mi; 31Ohun èlò orin mi pẹ̀lú sì di ti ọ̀fọ̀,

Щоденний ліміт досягнутий

Оновіть свій план, щоб продовжити використання можливостей ШІ з вищими щоденними лімітами.

Порівняти всі тарифи →