Mezmurlar 68
1Kí Ọlọ́run kí ó dìde, kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ kí ó fọ́nká; 2Bí ìjì ti ń fẹ́ èéfín lọ, 3Ṣùgbọ́n kí inú olódodo kí ó dùn 4Ẹ kọrin sí Ọlọ́run, Olúwa ni orúkọ rẹ̀, kí ẹ sì máa yọ̀ níwájú rẹ̀. 5Baba àwọn aláìní baba àti onídàájọ́ àwọn opó ni Ọlọ́run ní ibùgbé 6Ọlọ́run gbé aláìlera 7Nígbà tí ìwọ bá jáde lónìí níwájú àwọn ènìyàn rẹ, Ọlọ́run, Sela. 8Ilẹ̀ mì títí, 9Ìwọ fún wa ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ òjò, Ọlọ́run; 10Àwọn ènìyàn rẹ tẹ̀dó síbẹ̀ 11Olúwa ti pàṣẹ ọ̀rọ̀, 12“Àwọn ọba àti àwọn ológun yára sálọ; 13Nígbà tí ẹ̀yin dùbúlẹ̀ láàrín agbo ẹran, 14Nígbà tí Olódùmarè fọ́n àwọn ọba ká ní ilẹ̀ náà, 15Òkè Baṣani jẹ́ òkè Ọlọ́run; 16Kí ló dé tí ẹ̀yin fi ń ṣe ìlara, Olúwa fúnra rẹ̀ yóò máa gbé títí láé? 17Ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ni kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́run 18Ìwọ ti gòkè sí ibi gíga Olúwa Ọlọ́run lè máa bá wọn gbé. 19Olùbùkún ni Olúwa, Sela. 20Ọlọ́run wa jẹ́ Ọlọ́run tó ń gbàlà Olúwa Olódùmarè ni ó ń gbà wá lọ́wọ́ ikú. 21Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò tẹ orí àwọn ọ̀tá rẹ̀, 22Olúwa wí pé, “Èmi ó mú wọn wá láti Baṣani; 23kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó le pọ́n ní inú ẹ̀jẹ̀ àwọn ọ̀tá rẹ, 24Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run, 25Àwọn akọrin wà ní iwájú, àwọn olórin wà lẹ́yìn; 26Ẹ fi ìyìn fún Olúwa ní ẹgbẹgbẹ́; Olúwa ẹ̀yin tí ó ti orísun Israẹli wá. 27Níbẹ̀ ní ẹ̀yà kékeré Benjamini wà, tí ó ń darí wọn, 28Pàṣẹ agbára rẹ, Ọlọ́run; 29Nítorí tẹmpili rẹ ni Jerusalẹmu 30Bá àwọn ẹranko búburú wí, 31Àwọn ọmọ-aládé yóò wá láti Ejibiti; 32Kọrin sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ìjọba ayé, Olúwa, Sela. 33Sí ẹni tí ń gun ọ̀run dé ọ̀run àtijọ́ lókè, 34Kéde agbára Ọlọ́run, 35Ìwọ ní ẹ̀rù, Ọlọ́run, ní ibi mímọ́ rẹ;