YOR Çölde Sayım Bölüm 24

Çölde Sayım 24

YOR · Karşılaştır · Ses

1Nísinsin yìí nígbà tí Balaamu rí i wí pé ó tẹ́ Olúwa lọ́rùn láti bùkún àwọn Israẹli, kò lo ọ̀nà ìṣoṣó gẹ́gẹ́ bí ti ìgbà ìṣáájú, ṣùgbọ́n ó yí ojú rẹ̀ sí apá aginjù. 2Nígbà tí Balaamu wo ìta ó sì rí Israẹli tí wọ́n pàgọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì bà sórí rẹ̀ 3ó sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ rẹ̀, 4àsọtẹ́lẹ̀ ẹni tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 5“Àgọ́ rẹ ti dára tó, ìwọ Jakọbu, 6“Gẹ́gẹ́ bí àfonífojì tí ó tàn jáde, Olúwa gbìn, 7Omi yóò sàn láti inú garawa: 8“Ọlọ́run mú wọn jáde láti Ejibiti wá; 9Ó tẹríba ó sì dùbúlẹ̀ bí kìnnìún, 10Nígbà náà ni ìbínú Balaki sì dé sí Balaamu. Ó sì fi ọwọ́ lu ọwọ́ ó wí pé, “Mo pè ọ́ láti bú àwọn ọ̀tá mi ṣùgbọ́n o tún bùkún fún wọn nígbà mẹ́ta yìí. 11Nísinsin yìí sálọ sí ibùjókòó rẹ! Èmi ti rò láti sọ ọ́ di ẹni ńlá, ṣùgbọ́n Olúwa tí fà ọ́ sẹ́yìn láti gba èrè yìí.” 12Balaamu dá Balaki lóhùn, “Ǹjẹ́ èmi kò sọ fún àwọn ìránṣẹ́ tí o rán sí mi wí pé, 13‘Kódà bí Balaki bá fún mi ní ààfin rẹ̀ tí ó kún fún fàdákà àti wúrà, èmi kò le ṣe ohunkóhun lọ́wọ́ ara mi, yálà búburú tàbí rere, láti kọjá òfin Olúwa: ohun tí Olúwa bá wí ni èmi ó sọ’? 14Nísinsin yìí mò ń padà lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn mi, ṣùgbọ́n jẹ́ kí èmi kí ó kìlọ̀ fún ọ nítorí nǹkan tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí yóò ṣe sí àwọn ènìyàn rẹ ní ọjọ́ iwájú.” 15Nígbà náà ni ó bẹ̀rẹ̀ òwe: 16ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń wí, 17“Mo rí i, ṣùgbọ́n kì í ṣe ìsinsin yìí. 18Wọn yóò borí Edomu; 19Olórí yóò jáde láti Jakọbu 20Nígbà náà ni Balaamu rí Amaleki ó sì bẹ̀rẹ̀ òwe: 21Nígbà náà ní ó rí ará Keni ó sì bẹ̀rẹ̀ òwe: 22síbẹ̀ ẹ̀yin ará Keni ni yóò di píparun 23Nígbà náà ni ó bẹ̀rẹ̀ òwe rẹ̀: 24Ọkọ̀ yóò wá láti ibùdókọ̀ Kittimu; 25Nígbà náà ni Balaamu dìde ó sì padà sí ilé rẹ̀, Balaki sì lọ ní ọ̀nà tirẹ̀.

Günlük Limit Ulaşıldı

Yapay Zeka özelliklerini daha yüksek günlük limitlerle kullanmaya devam etmek için planınızı yükseltin.

Tüm planları karşılaştır →