YOR Mika Bölüm 5

Mika 5

YOR · Karşılaştır · Ses

1Nísinsin yìí, kó àwọn ọ̀wọ́ ogun rẹ jọ, 2“Ṣùgbọ́n ìwọ, Bẹtilẹhẹmu Efrata, 3Nítorí náà Israẹli yóò di kíkọ̀sílẹ̀ pátápátá 4Òun yóò sì dúró, Olúwa, Olúwa Ọlọ́run rẹ̀. 5Òun yóò sì jẹ́ àlàáfíà wọn. 6Wọn yóò sì fi idà pa ilẹ̀ Asiria run, 7Ìyókù Jakọbu yóò sì wà Olúwa wa, 8Ìyókù Jakọbu yóò sì wà láàrín àwọn aláìkọlà 9A ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀, 10“Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí, 11Èmi yóò sì pa ilẹ̀ ìlú ńlá rẹ̀ run, 12Èmi yóò gé ìwà àjẹ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, 13Èmi yóò pa àwọn ère fínfín rẹ̀ run, 14Èmi yóò fa ère Aṣerah tu kúrò láàrín rẹ̀, 15Èmi yóò gbẹ̀san ní ìbínú àti ìrunú

Günlük Limit Ulaşıldı

Yapay Zeka özelliklerini daha yüksek günlük limitlerle kullanmaya devam etmek için planınızı yükseltin.

Tüm planları karşılaştır →