YOR Hezekiel Bölüm 19

Hezekiel 19

YOR · Karşılaştır · Ses

1Kọ orin ọ̀fọ̀ nítorí àwọn ọmọ-aládé Israẹli 2wí pé: 3Ó sì tọ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ dàgbà, ó sì di kìnnìún tó ní agbára, 4Àwọn orílẹ̀-èdè gbọ́ nípa rẹ̀, 5“ ‘Nígbà tí abo kìnnìún yìí rí pé ìrètí rẹ̀ sì jásí asán, 6Ó sì ń rìn káàkiri láàrín àwọn kìnnìún nítorí pé ó ti lágbára, 7Ó sì wó odi wọn palẹ̀ ó sì sọ àwọn ìlú wọn di ahoro. 8Nígbà náà ni àwọn orílẹ̀-èdè dìde sí i, 9Wọn fi ìwọ̀ gbé e sínú àgò, wọn mú un lọ sí ọ̀dọ̀ ọba Babeli, 10“ ‘Ìyá rẹ dàbí àjàrà nínú ọgbà àjàrà rẹ̀; 11Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ lágbára tó láti fi ṣe ọ̀pá àṣẹ ìjòyè, 12Ṣùgbọ́n ó fà á tu ní ìrunú, 13Báyìí, a tún ún gbìn sínú aṣálẹ̀ 14Iná sì jáde láti ọ̀kan lára ẹ̀ka rẹ̀

Günlük Limit Ulaşıldı

Yapay Zeka özelliklerini daha yüksek günlük limitlerle kullanmaya devam etmek için planınızı yükseltin.

Tüm planları karşılaştır →