สดุดี 66
1Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ilẹ̀ gbogbo! 2Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀; 3Ẹ wí fún Ọlọ́run pé, “Ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ rẹ! 4Gbogbo ayé ń wólẹ̀ fún ọ; Sela. 5Ẹ wá wo ohun tí Ọlọ́run ṣe, 6Ó yí òkun padà sí ilẹ̀ gbígbẹ, 7Ó ń jẹ ọba títí láé nípa agbára rẹ̀, Sela. 8Ẹ yin Ọlọ́run wa, ẹ̀yin ènìyàn, 9Ó ti dá ààbò bo ẹ̀mí wa, 10Nítorí ìwọ, Ọlọ́run, dán wa wò; 11Ìwọ mú wa wá sínú ẹ̀wọ̀n 12Ìwọ mú àwọn ènìyàn gún wá ní orí 13Èmi ó wá sí tẹmpili rẹ pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun, 14ẹ̀jẹ́ tí ètè mi jẹ́, tí ẹnu mi sì sọ 15Èmi ó rú ẹbọ sísun ọlọ́ràá sí ọ, Sela. 16Ẹ wá gbọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run; 17Mo fi ẹnu mi kígbe sókè sí i, 18Bí èmi bá gba ẹ̀ṣẹ̀ ní àyà mi, 19ṣùgbọ́n Ọlọ́run gbọ́ nítòótọ́ 20Ìyìn ni fún Ọlọ́run