อิสยาห์ 45
1“Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ẹni òróró rẹ̀, 2Èmi yóò lọ síwájú rẹ, 3Èmi yóò sì fún ọ ní àwọn ọrọ̀ ibi òkùnkùn, Olúwa, 4Nítorí Jakọbu ìránṣẹ́ mi 5Èmi ni Olúwa, àti pé kò sí ẹlòmíràn; 6tí o fi jẹ́ pé láti ìlà-oòrùn Olúwa, lẹ́yìn mi kò sí ẹlòmíràn mọ́. 7Mo dá ìmọ́lẹ̀, mo sì dá òkùnkùn, Olúwa ni ó ṣe nǹkan wọ̀nyí. 8“Ìwọ ọ̀run lókè rọ òjò òdodo sílẹ̀; Olúwa ni ó ti dá a. 9“Ègbé ni fún ènìyàn tí ó ń bá Ẹlẹ́dàá rẹ̀ jà, 10Ègbé ni fún ẹni tí ó sọ fún baba rẹ̀ pé, 11“Ohun tí Olúwa wí nìyìí, 12Èmi ni ẹni tí ó dá ilẹ̀ ayé 13Èmi yóò gbé Kirusi sókè nínú òdodo mi. Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.” 14Ohun tí Olúwa wí nìyìí: 15Nítòótọ́ ìwọ jẹ́ Ọlọ́run tí ó fi ara rẹ̀ pamọ́, 16Gbogbo àwọn tí ó ń gbẹ́ ère ni ojú yóò tì 17Ṣùgbọ́n Israẹli ni a ó gbàlà láti ọwọ́ Olúwa 18Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí, Olúwa, 19Èmi kò sọ̀rọ̀ níbi tí ó fi ara sin, Olúwa sọ òtítọ́, 20“Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ sì wá; 21Jẹ́ kí a mọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀, fihàn wá, Olúwa? 22“Yípadà sí mi kí a sì gbà ọ́ là, 23Nípa èmi tìkára mi ni mo ti búra, 24Wọn yóò sọ ní ti èmi, ‘Nínú Olúwa nìkan ni 25Ṣùgbọ́n nínú Olúwa gbogbo àwọn ìran Israẹli