ฮาบากุก 2
1Èmi yóò dúró lórí ibusọ́ mi láti máa wòye, Olúwa 2Nígbà náà ni Olúwa dáhùn pé, 3Nítorí ìṣípayá náà jẹ́ tí ìgbà kan tí a múra sílẹ̀ dè; 4“Kíyèsi, ọkàn rẹ tí ó gbéga, 5Bẹ́ẹ̀ ni pẹ̀lú, nítorí tí ọtí wáìnì ni ẹ̀tàn, 6“Gbogbo àwọn wọ̀nyí kì yóò máa pa òwe sí i tí wọn yóò sì máa kọ orin òwe sí i wí pé, 7Ǹjẹ́ ẹni ti ó yọ ọ́ lẹ́nu, kí yóò ha dìde ní òjijì? 8Nítorí ìwọ ti kó Orílẹ̀-èdè púpọ̀, 9“Ègbé ni fún ẹni tí ń jẹ èrè ìjẹkújẹ sí ilé rẹ̀, 10Ìwọ ti gbìmọ̀ ìtìjú sí ilé rẹ 11Nítorí tí òkúta yóò kígbe jáde láti inú ògiri wá, 12“Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ẹ̀jẹ̀ kọ́ ìlú, 13Olúwa àwọn ọmọ-ogun kò ha ti ṣètò rẹ̀ pé 14Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo Olúwa, 15“Ègbé ni fún ẹni tí ó fi ohun mímu fún aládùúgbò rẹ̀, 16Ìtìjú yóò bò ọ́ dípò ògo, ìwọ náà mu pẹ̀lú Olúwa, yóò yípadà sí ọ, 17Nítorí ìwà ipá tí ó tí hù sí Lebanoni yóò bò ọ́, 18“Èrè kí ni òrìṣà ni, tí oníṣọ̀nà rẹ̀ fi gbẹ́ ẹ, 19Ègbé ni fún ẹni ti ń sọ fún igi pé, ‘Di alààyè?’ 20Ṣùgbọ́n Olúwa wà nínú tẹmpili mímọ́ rẹ̀;