YOR อิสยาห์ บท 21

อิสยาห์ 21

1̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan aginjù lẹ́bàá Òkun. 2Ìran tí a ń fojú ṣọ́nà fún ni a ti fihàn mí 3Pẹ̀lú èyí, ìrora mu mi lára gírígírí, 4Ọkàn mí dàrú, 5Wọ́n tẹ́ tábìlì, 6Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: 7Nígbà tí ó bá rí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun 8Òun sì kígbe pé, kìnnìún kan, 9Wò ó, ọkùnrin kan ni ó ń bọ̀ wá yìí nínú kẹ̀kẹ́ ogun 10Ẹ̀yin ènìyàn mi, tí a gún mọ́lẹ̀ ní ilẹ̀ ìpakà, Olúwa àwọn ọmọ-ogun, 11Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Dumahi. 12Alóre náà dáhùn wí pé, 13Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Arabia. 14gbé omi wá fún àwọn tí òǹgbẹ ń gbẹ; 15Wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ idà, 16Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi: “Láàrín ọdún kan, gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀fà tí ó wà lábẹ́ ọgbà, í ti í kà á, gbogbo ògo ìlú Kedari yóò wá sí òpin. 17Àwọn tafàtafà tí ó sálà, àwọn jagunjagun ìlú Kedari kò ní tó nǹkan.” Olúwa, Ọlọ́run Israẹli ni ó ti sọ̀rọ̀.

ถึงลิมิตรายวัน

อัปเกรดแพ็กเกจของคุณเพื่อใช้คุณสมบัติ AI ต่อไปด้วยลิมิตรายวันที่สูงขึ้น

เปรียบเทียบแพ็กเกจทั้งหมด →