YOR Jeremiah Sura 10

Jeremiah 10

YOR · Linganisha · Sauti

1Gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Olúwa sọ fún yín ẹ̀yin ilé Israẹli. 2Báyìí ni Olúwa wí: 3Nítorí pé asán ni àṣà àwọn ènìyàn, 4Wọ́n fi fàdákà àti wúrà ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́. 5Wọ́n wé mọ́ igi bí ẹ̀gúnsí inú oko, 6Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ Olúwa; 7Ta ni kò yẹ kí ó bẹ̀rù rẹ? 8Gbogbo wọn jẹ́ aláìlóye àti aṣiwèrè, 9Fàdákà tí a ti kàn ni a mú wá láti Tarṣiṣi, 10Ṣùgbọ́n Olúwa ni Ọlọ́run tòótọ́, 11“Sọ èyí fún wọn: ‘Àwọn ọlọ́run kéékèèké tí kò dá ọ̀run àti ayé ni yóò ṣègbé láti ayé àti ní abẹ́ ọ̀run.’ ” 12Ọlọ́run dá ayé pẹ̀lú agbára rẹ̀, 13Nígbà tí ó bá sán àrá, àwọn omi lọ́run a sì pariwo; 14Gbogbo ènìyàn jẹ́ aṣiwèrè àti aláìnímọ̀, 15Asán ni wọ́n, iṣẹ́ ìṣìnà; 16Ẹni tí ó bá jẹ́ ìpín Jakọbu kò sì dàbí èyí, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀. 17Kó ẹrù rẹ kúrò láti fi ilẹ̀ náà sílẹ̀ 18Nítorí èyí ni Olúwa wí: 19Ègbé ni fún mi nítorí ìpalára mi! 20Àgọ́ mi bàjẹ́, 21Àwọn olùṣọ́-àgùntàn jẹ́ aṣiwèrè, Olúwa: 22Fetísílẹ̀! ariwo igbe ń bọ̀, 23Èmi mọ̀ Olúwa wí pé ọ̀nà ènìyàn kì í ṣe ti ara rẹ̀, 24Tún mi ṣe Olúwa, pẹ̀lú ìdájọ́ nìkan 25Tú ìbínú rẹ jáde sórí àwọn orílẹ̀-èdè

Kikomo cha Kila Siku Kimefikia

Boresha mpango wako ili kuendelea na matumizi ya vipengele vya AI na mipango ya juu ya kila siku.

Linganisha mipango yote →